Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà (President of the Federal Republic of Nigeria) tàbì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lásán ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà.[2] Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà náà tún ni Aláṣẹ pátápátá àwọn ológun Nàìjíríà. Àwọn ará Nàìjíríà ún dìbò yan ààrẹ fún ọdún mẹ́rin. Àwọn ipò ààrẹ, àwọn agbára, àti àwọn oyè olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba jẹ́ dídàpọ̀ sí ipò ààrẹ lábẹ́ Òfin-Ibágbépọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà odún 1979. Ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, Bola Tinubu, bọ́ sí orí àga ní May 29, 2023, gẹ́gẹ́bí ààrẹ 16k Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà.[3]
Quick Facts Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà President of the Federal Republic of Nigeria, Style ...
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà President of the Federal Republic of Nigeria | |
---|---|
Executive Branch of the Federal Government | |
Style | Mr. President His Excellency |
Member of | Federal Executive Council National Security Council |
Residence | Aso Villa |
Seat | Abuja, F.C.T. |
Appointer | Direct popular election |
Iye ìgbà | Four years, renewable once |
Constituting instrument | Òfin-ìbágbépọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà |
Ẹni àkọ́kọ́ | Nnamdi Azikiwe |
Formation | Àdàkọ:Date and age |
Deputy | Vice President of Nigeria |
Owó osù | ₦14,000,000 annually[1] |
Website | statehouse.gov.ng |
Close