Émile Derlin Zinsou
From Wikipedia, the free encyclopedia
Émile Derlin Zinsou tí wọ́n bí ní ejò kẹtalélógú oṣù kẹta ọdún 1918 tí ó sì papò da ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù keje 2016 [1] jẹ́ olóṣèlú, ònímọ̀ ìjìnlẹ̀ físíìsì tí ó sì tún jẹ́ ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí Dahomey kí ó tó di orílẹ̀-èdè Benin pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn ọmọ ológun ilẹ̀ Dahomey láàrín ọdún 1968 sí ọdún 1969 Zinsou wà lára àwọn tí wọ́n buwọ́ lu [[òfin tí da àjọ African Union sílẹ̀ ní ọjọ́ Kejìlá oṣù keje ọdún 2000 ní orílẹ̀-èdè Togo.
Quick Facts President of Dahomey, Asíwájú ...
Émile Derlin Henri Zinsou | |
---|---|
Emile Zinsou | |
President of Dahomey | |
In office 17 July 1968 – 10 December 1969 | |
Asíwájú | Alphonse Amadou Alley |
Arọ́pò | Iropa Maurice Kouandété |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | (1918-03-23)23 Oṣù Kẹta 1918 Ouidah, Dahomey |
Aláìsí | 28 July 2016(2016-07-28) (ọmọ ọdún 98) Cotonou, Benin |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Florence Atayi Guy Gaspard |
Profession | Politician, physician |
Signature |
Close