Ìmúdọ́gba Àyipàdà Ójú Ọjọ́
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àṣamubadọgba Lori Àyipada Óju Ọjọ jẹ ọna a ti ṣè àtunṣè lori ipa ayipada óju ọjọ. Èyi jẹ ipa ti oun ṣẹlẹ lọwọ tabi eyi to nbọ. Àṣamubadọgbà jẹ ọna lati dinku tabi dina abùrù kuró fun ọmọ èniyan. Èyi jẹ ọnà fun ọpọlọpọ anfani, èniyan ni lati dasi ọrọ ayipada ójù ọjọ. Óriṣiriṣi àgbèkalẹ ati ètó lo wa ni Àṣamubadọgba lati dina aburu tabi ipa awọn ìṣẹ̀lẹ̀ yii[1][2][3].
Ìdi fun Àṣamubadọgba gbẹ̀kẹlè agbègbè kan si ìkèji. Èyi lè jẹ abùrù fun èniyan tabi ayika. Àṣamubadọgba ṣè pataki fun awọn órilẹ èdè to ti dàgbà sókè nitori awọn lo maa nfarapà julọ ninu ayipada ójù ọjọ nitori idi èyi wọn maa kóju ipà ìṣẹlẹ naa. Àṣamubadọgba tobi fun ounjẹ, ómi, ọrọ àjè, iṣẹ tabi ówó ójọ[4][5].
Ìgbaradi ati ètó fun Àṣamubadọgba ṣè pataki órilẹ èdè lati koju abùrù to wa ni ayipàdà ójù ọjọ. Èyi ló mu ki ipèlè ijọba lati óriṣiriṣi agbègbè ṣè agbèkalẹ ètó. Awọn órilẹ ede to ti dagbàsókè maa nwa ówó lati ókè ókun ni ọna lati ṣè agbèkalẹ ètó lati ṣiṣẹ lóri Àṣamubadọgba. Ètó yii ni lati mujutó awọn ifarapa tabi èwù tolè ṣuyọ latari ayipadà ójù ọjọ. Iye owo Àṣamubadọgba ayipàdà óju ọjọ jẹ billionu dollar lọdọdun fun ọdun mẹwa to nbọ. Fun ọpọlọpọ igba, Iye owo naa dinku si bibajẹ to fẹ̀ ṣiṣẹ lori.[6].
Ìwadi lori Àṣamubadọgba àyipàdà ójù ọjọ bẹrẹ lati ọdun 1990s. Óriṣiriṣi ọrọ lori rẹ losi ti lèkun lati igbànà. Àṣamubadọgba di ófin to mulẹ ni ọdun 2010s lati igba adehun ilẹ Paris to si sọdi ọrọ pataki fun iwàdi ófin[7][8]. Ìwadi ijinlẹ sayẹnsi lori Àṣamubadọgba ayipàdà ójù ọjọ bẹrẹ pẹlù Ìtu si wẹwẹ ìpa ayipada óju ọjọ lori eniyàn, àyikà ati Ìlànà ìbáṣepọ̀ àwọn ohun ẹlẹ́mìí pẹ̀lú àyíká. Awọn Ipà nàà bóri ìṣẹmi, ètó iwósan ati àyika. Ìpayi lè jẹ ayipàdà ìkórè oun ọgbin, àlèkun ìkun ómi ati ọ̀gbẹlẹ. Ìtu si wẹwẹ awọn ipa yii jẹ ọna pataki lati mọ Àṣamubadọgba ti ọjọ iwaju[9].