Christopher Oluwole Rotimi
From Wikipedia, the free encyclopedia
Christopher Oluwole Rotimi (ọjọ́-ìbí; Ọjọ́ Ogún Oṣù Kejì, Ọdún 1935) jẹ́ Balogun àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Nàìjíríà tó ti fẹ̀yìntì, aláṣejúṣe àti olóṣèlú, ó ṣiṣẹ́ lásìkò Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà, ó sì jẹ́ Gómìnà àwọn ìpínlẹ̀ ìwọ̀orùn lásìkò tí Nàìjíríà wà lábé ìjọba ológun láti ọdún 1971 sí 1975. Oluwole Rotimi di Aṣojú Nàìjíríà sí Orílẹ̀ èdè Améríkà ní ọdún 2007.[1]
Fún àwọn mìíràn tó ń jẹ́ Rotimi, ẹ wo Rotimi.
Quick Facts Brigadier general, Governor Western State ...
Brigadier general Christopher Oluwole Rotimi | |
---|---|
Governor Western State | |
In office 1 April 1971 – July 1975 | |
Asíwájú | Robert Adeyinka Adebayo |
Arọ́pò | Akin Aduwo |
Ambassador of Nigeria to the United States of America | |
In office March 2008 – 9 October 2009 | |
Lieutenant | Null |
Asíwájú | George Obiozor |
Arọ́pò | Tunde Adeniran |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kejì 1935 (1935-02-20) (ọmọ ọdún 89) Abeokuta, Ogun State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Unknown |
Alma mater | King's College, Lagos University College Ibadan |
Occupation | Soldier |
Military service | |
Allegiance | Nigeria |
Branch/service | Adigun Nàìjíríà |
Rank | Brigadier general |
Close